Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ INÚ ÌWÉ YÌÍ
Àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ ní May 4-10, 2026
2 Bá A Ṣe Lè Di Olùkọ́ Tó Já Fáfá Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù
Àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ ní May 11-17, 2026
8 Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà Ọba Aláṣẹ Ayé Àtọ̀run
Àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ ní May 18-24, 2026
14 Ohun Tá A Lè Ṣe Kí Ohunkóhun Má Bàa Pín Ọkàn Wa Níyà
Àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ ní May 25-31, 2026
20 Wàá “Ṣàṣeyọrí” Tó O Bá Ní Ìjìnlẹ̀ Òye
Àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ ní June 1-7, 2026
26 Ohun Tó Lè Fún Wa Láyọ̀ Báwọn Èèyàn Tiẹ̀ Kórìíra Wa
32 Àwọn Tí Bíbélì Sọ̀rọ̀ Wọn—Jẹ́ Onígboyà àti Olóòótọ́ Bíi Ti Bẹnáyà