ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • g99 7/8 ojú ìwé 15
  • Bíbélì Ló Kọ́kọ́ Sọ Ọ́

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Bíbélì Ló Kọ́kọ́ Sọ Ọ́
  • Jí!—1999
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Bó O Ṣe Lè Wá Ẹsẹ Ìwé Mímọ́ Nínú Bíbélì Rẹ
    Àkójọ Àpilẹ̀kọ àti Fídíò
  • Àtẹ Àwọn Ọjọ́ Ìṣẹ̀lẹ̀
    Kí Ló Wà Nínú Bíbélì?
  • Martin Luther—Ogún Tó Fi Sílẹ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2003
  • Dídánudúró Bó Ṣe Yẹ
    Jàǹfààní Nínú Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run
Àwọn Míì
Jí!—1999
g99 7/8 ojú ìwé 15

Bíbélì Ló Kọ́kọ́ Sọ Ọ́

● “A kì í ṣàdédé bẹ̀rẹ̀ ìjíròrò, bẹ́ẹ̀ ni kì í jẹ́ ní kánjúkánjú. A kì í fìkánjú béèrè ìbéèrè, bó ti wù kí ìbéèrè ọ̀hún ṣe pàtàkì tó, a kì í sì í fagbára múni dáhùn. Ìdánudúró díẹ̀ tí ń fúnni láyè láti ronú ni ọ̀nà tí ojúlówó ọmọlúwàbí gbà ń bẹ̀rẹ̀ ìjíròrò tó sì fi ń bá a nìṣó. Dídákẹ́ nítumọ̀ lójú àwọn ẹ̀yà Lakota . . . Wọ́n máa ń ṣe [èyí] gẹ́gẹ́ bí ojúlówó ìwà ìbọ̀wọ̀fúnni àti títẹ̀lé ìlànà náà tó sọ pé, ‘ńṣe la máa ń ronú ká tó sọ̀rọ̀.’”—Luther Standing Bear, olóye Oglala ti ẹ̀yà Sioux, (nǹkan bí 1868 sí 1939).

“Kí ẹ mọ èyí, ẹ̀yin ará mi olùfẹ́ ọ̀wọ́n. Kí olúkúlùkù ènìyàn yára nípa ọ̀rọ̀ gbígbọ́, lọ́ra nípa ọ̀rọ̀ sísọ, lọ́ra nípa ìrunú.”—Jákọ́bù 1:19, Bíbélì (ọ̀rúndún kìíní Sànmánì Tiwa).

“Ọkàn-àyà olódodo máa ń ṣe àṣàrò láti lè dáhùn, ṣùgbọ́n ẹnu àwọn ẹni burúkú máa ń tú àwọn ohun búburú jáde.”—Òwe 15:28, Bíbélì (nǹkan bí ọ̀rúndún kẹjọ ṣááju Sànmánì Tiwa).

“Gbogbo ẹ̀mí rẹ̀ ni arìndìn ń tú jáde, ṣùgbọ́n ẹni tí ó gbọ́n a máa mú kí ó pa rọ́rọ́ títí dé ìkẹyìn.”—Òwe 29:11, Bíbélì (nǹkan bí ọ̀rúndún kẹjọ ṣááju Sànmánì Tiwa).

[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 15]

Fọ́tò látọwọ́ David Barry, ti Denver Public Library, Western History Collection

    Yorùbá Publications (1987-2026)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́