Ojú ìwé 2
O Lè Kápá Àìfararọ! 3-13
A ti pè é ní “ayọ́kẹ́lẹ́pani” àti “ayọ́kẹ́lẹ́ṣọṣẹ́.” Kí ni o lè ṣe nípa àìfararọ?
Eyín Erin—Báwo Ló Ṣe Níye Lórí Tó? 15
Bí àwọn ènìyàn ṣe ń wá eyín erin fún àwọn ohun tí a fi ń tẹ dùrù, ohun ọ̀ṣọ́ àti ọnà gbígbẹ́ tó burú jáì. Àmọ́ erin mélòó ló ti lọ sí i?
Mo La Ìjàǹbá Ọkọ̀ Òfuurufú Nọnba 801 Já 23
Nígbà tí ọkọ̀ òfuurufú ẹ̀yà 747 kan já ní Guam, ènìyàn 26 ló là á já. Ka ìròyìn wíwọnilọ́kàn tí ọ̀kan lára wọ́n sọ.