Sunday
“Aláyọ̀ ni ojú yín torí wọ́n rí àti etí yín torí wọ́n gbọ́”—Mátíù 13:16
Àárọ̀
9:20 Fídíò Orin
9:30 Orin 68 àti Àdúrà
9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Ohun Tá A Kọ́ Nínú Àwọn Àpèjúwe Jésù
• Oríṣi Ilẹ̀ Mẹ́rin (Mátíù 13:18-23)
• Àlìkámà àti Èpò (Mátíù 13:24-30)
• Hóró Músítádì (Mátíù 13:31, 32)
• Ìwúkàrà (Mátíù 13:33)
• Àwọ̀n (Mátíù 13:47-50)
11:00 Orin 64 àti Ìfilọ̀
11:10 ÀSỌYÉ FÚN GBOGBO ÈÈYÀN: Ṣé O Ti Rí Ìṣúra Náà? (Mátíù 13:44-46)
11:40 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́
12:10 Orin 140 àti Àkókò Ìsinmi
Ọ̀sán
1:35 Fídíò Orin
1:45 Orin 108
1:50 FÍDÍÒ ÌTÀN BÍBÉLÌ:
Ìhìn Rere Látọ̀dọ̀ Jésù: Abala 6
“Ṣé Ìwọ Ni Ẹni Tó Ń Bọ̀?” (Mátíù 8:5-13; 11:2–13:53; Máàkù 3:19–4:34; Lúùkù 7:1–8:21)
2:35 Orin 120 àti Ìfilọ̀
2:45 Kí Lo Rí Kọ́?
2:55 “Aláyọ̀ Ni Ojú Yín Torí Wọ́n Rí” (Mátíù 7:1-5; 13:16, 17; Lúùkù 6:46-49; 10:21; Jòhánù 17:6; Jémíìsì 1:22-25)
3:45 Orin 163 àti Àdúrà Ìparí