ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • CO-pgm26 ojú ìwé 4-5
  • Saturday

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Saturday
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2026
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Friday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2025
  • Sunday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2026
  • Friday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2026
  • Friday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2024
Àwọn Míì
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2026
CO-pgm26 ojú ìwé 4-5
Àwòrán: Ohun tá a máa gbádùn lọ́jọ́ Saturday. 1. Jésù Kristi. 2. Àwọn èèyàn kan jókòó, wọ́n ń tẹ́tí sí ohun tí Jésù ń sọ. Àwọn Farisí dúró sítòsí, inú ń bí wọn bí wọ́n ṣe ń gbọ́ ọ̀rọ̀ Jésù.

Saturday

“Ayọ̀ púpọ̀ wà nínú fífúnni ju èyí tó wà nínú rírígbà lọ”—Ìṣe 20:35

Àárọ̀

  • 9:20 Fídíò Orin

  • 9:30 Orin 111 àti Àdúrà

  • 9:40 ‘Ó La Ẹnu Rẹ̀, Ó sì Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Kọ́ Wọn’ (Mátíù 5:1, 2)

  • 9:50 FÍDÍÒ ÌTÀN BÍBÉLÌ:

    Ìhìn Rere Látọ̀dọ̀ Jésù: Abala 5

    “Bó Ṣe Ń Kọ́ni Lẹ́kọ̀ọ́ Yà Wọ́n Lẹ́nu” (Mátíù 5:3–7:29; Lúùkù 6:17-49)

  • 10:25 Orin 89 àti Ìfilọ̀

  • 10:35 Àwọn Nǹkan Wo Ni Kì Í Jẹ́ Kéèyàn Láyọ̀? (Lúùkù 6:24-26)

  • 10:50 Ṣé O Máa Ń Fòye Mọ Ìlànà Tó Wà Nínú Òfin? (Mátíù 5:17-48)

  • 11:15 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Ohun Tá A Kọ́ Nípa Ibi tí Jésù Dé

    • • Iyọ̀ àti Ìmọ́lẹ̀ (Mátíù 5:13-16)

    • • Ewéko àti Ẹranko (Jẹ́nẹ́sísì 1:28, 29; Mátíù 6:19, 26, 28; 7:6, 10, 15, 16)

  • 11:40 ÌRÌBỌMI: ‘Baba Rẹ Tó Ń Rí Ohun Tó Wà ní Ìkọ̀kọ̀ Máa San Ọ́ Lẹ́san’ (Mátíù 6:6)

  • 12:10 Orin 51 àti Àkókò Ìsinmi

Ọ̀sán

  • 1:35 Fídíò Orin

  • 1:45 Orin 125

  • 1:50 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: “Aláyọ̀ Ni . . . ”

    • • “Àwọn Tó Ń Wá Ìtọ́sọ́nà Ọlọ́run” (Mátíù 5:3)

    • • “Àwọn Tó Ń Ṣọ̀fọ̀” (Mátíù 5:4)

    • • “Àwọn Oníwà Tútù” (Mátíù 5:5)

    • • “Àwọn Tí Ebi Òdodo Ń Pa, Tí Òùngbẹ Òdodo sì Ń Gbẹ” (Mátíù 5:6)

    • • “Àwọn Aláàánú” (Mátíù 5:7)

    • • “Àwọn Tí Ọkàn Wọn Mọ́” (Mátíù 5:8)

    • • “Àwọn Tó Ń Wá Àlàáfíà” (Mátíù 5:9)

    • • “Àwọn Tí Wọ́n Ṣe Inúnibíni Sí Nítorí Òdodo” (Mátíù 5:10)

    • • “Yín Tí Àwọn Èèyàn Bá Pẹ̀gàn Yín” (Mátíù 5:11, 12)

  • 3:20 Orin 81 àti Ìfilọ̀

  • 3:30 “Kí Ló Dé Tí Ẹ̀ Ń Ṣàníyàn?” (Mátíù 6:19-33)

  • 3:55 “Ẹ Gba Ẹnubodè Tóóró Wọlé” (Mátíù 7:1-5, 12-14, 16-18, 24-27)

  • 4:30 Orin 21 àti Àdúrà Ìparí

    Yorùbá Publications (1987-2026)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́