ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • ijwbq àpilẹ̀kọ 19
  • Ṣé Ó Burú Kí Kristẹni Lo Oògùn Tí Kì Í Jẹ́ Kéèyàn Lóyún?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ṣé Ó Burú Kí Kristẹni Lo Oògùn Tí Kì Í Jẹ́ Kéèyàn Lóyún?
  • Ohun Tí Bíbélì Sọ
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ohun tí Bíbélì sọ
  • Ṣó Dáa Kéèyàn Máa Lo Oògùn Máàjóyúndúró?
    Jí!—2008
  • Bíbélì Dáhùn Ìbéèrè Mẹ́wàá Nípa Ìbálòpọ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
  • Ta Ló Yẹ Kó Pinnu Bí Ìdílé Yóò Ṣe Tóbi Tó?
    Jí!—1996
  • “Àwọn Ọmọ Jẹ́ Ogún Láti Ọ̀dọ̀ Jèhófà”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2026
Àwọn Míì
Ohun Tí Bíbélì Sọ
ijwbq àpilẹ̀kọ 19
Tọkọtaya tó ń rìn ní etíkun

Ṣé Ó Burú Kí Kristẹni Lo Oògùn Tí Kì Í Jẹ́ Kéèyàn Lóyún?

Ohun tí Bíbélì sọ

Jésù kò pàṣẹ pé kí àwọn ọmọlẹ́yìn òun bímọ tàbí kí wọ́n má ṣe bímọ. Àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ náà kò sì sọ ohun tó jọ bẹ́ẹ̀. Kò sí ibì kankan tí Bíbélì ti sọ pé èèyàn kò gbọ́dọ̀ fètò sọ́mọ bíbí. Ìlànà tó wà nínú Róòmù 14:12 ló yẹ ká tẹ̀ lé lórí ọ̀rọ̀ yìí, ó sọ pé: “Olúkúlùkù wa ni yóò ṣe ìjíhìn ara rẹ̀ fún Ọlọ́run.”

Nítorí náà, tọkọtaya ló máa pinnu bóyá àwọn fẹ́ bímọ tàbí wọn kò fẹ́. Wọ́n tún lè pinnu iye ọmọ tí wọ́n fẹ́ bí àti ìgbà tí wọ́n fẹ́ bí wọn. Bó tilẹ̀ jẹ́ pé tọkọtaya kan kò gbọ́dọ̀ lo oògùn tó ń ṣẹ́yún, síbẹ̀ wọ́n lè yàn bí wọ́n bá fẹ́ láti lo oògùn tí kì í jẹ́ kéèyàn lóyún. Ẹnì kankan kò gbọ́dọ̀ dá wọn lẹ́bi lórí èyí.—Róòmù 14:4, 10-13.

    Yorùbá Publications (1987-2026)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́