Ojú ìwé 2
Ǹjẹ́ Ó Yẹ Kí O Máa Sọ̀rọ̀ Nípa Ìsìn? 3-9
Láti bá ẹlòmíràn sọ̀rọ̀ nípa ìsìn nítùnbí-ǹ-nùbí lè ṣòro. Kọ́ bí o ṣe lè báni sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀ lọ́nà tí yóò ṣàǹfààní ní ti gidi.
Àádọ́ta Ọdún Lábẹ́ Ìgbonimọ́lẹ̀ Ìjọba Oníkùmọ̀ 10
Mọ bí ó ṣe rí láti jìyà lábẹ́ ìṣàkóso Nazi àti lábẹ́ ìnilára ìjọba Soviet.
Kí Ló Burú Nínú Òfófó Ṣíṣe? 17
Èé ṣe tí òfófó ṣíṣe fi wọ́pọ̀ gan-an, síbẹ̀ kí ló sábà máa ń tìdí rẹ̀ yọ? Kí lo lè ṣe sí i?