Ojú ìwé 2
A Ha Ń Yí Ojú Ọjọ́ Wa Padà Bí? 3-10
Ọ̀pọ̀ àwọn onímọ̀ sáyẹ́ǹsì ń bẹ̀rù pé ipò ojú ọjọ́ ilẹ̀ ayé ń móoru sí i àti pé irú ìyípadà bẹ́ẹ̀ lè fa àjálù ní ọ̀rúndún tí ń bọ̀. Ẹ̀rù tí ń bà wọ́n yìí ha bẹ́tọ̀ọ́ mu bí? Bí ó bá rí bẹ́ẹ̀, ènìyàn ló ha ni ẹ̀bi náà bí? A ha ní láti dààmú nípa ọjọ́ ọ̀la pílánẹ́ẹ̀tì wa bí?
Ta Ló Yẹ Kí N Fi Ṣe Àwòkọ́ṣe? 12
Ọ̀pọ̀ èwe ń káṣà àwọn gbajúgbajà òṣèré sinimá, àwọn akọrin, àti àwọn eléré ìdárayá. Irú àwọn tí ìwọ fi ń ṣe àwòkọ́ṣe ha ṣe nǹkan bí?
Àwọn Erékùṣù Tí Ń Kóra Jọ 24
Àwọn erékùṣù Hawaii ń múni finú wòye ibi alálàáfíà kan ní ilẹ̀ olóoru, àwọn etíkun tí oòrùn ti ń mú, àti ẹ̀fúùfù atura tí ó fẹ́rẹ̀ẹ́ máà dáwọ́ dúró. Báwo ni wọ́n ṣe dé ibẹ̀?
[Àwọn àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Mountain High Maps® Copyright © 1997 Digital Wisdom, Inc.
Ẹ̀YÌN ÌWÉ: Richard Kaylin/Tony Stone Images
Dept. of Interior, National Park Service