ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • g98 3/8 ojú ìwé 2
  • Ojú ìwé 2

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ojú ìwé 2
  • Jí!—1998
  • Ìsọ̀rí
  • Báwo Ni A Ṣe Lè Gbẹ́kẹ̀ Lé Sáyẹ́ǹsì Tó? 3-12
  • Kí Ló Ṣẹlẹ̀ sí Ẹ̀yà Apache? 13
  • Àwọn Kristẹni àti Ètò Kẹ́lẹ́gbẹ́mẹgbẹ́ 22
Jí!—1998
g98 3/8 ojú ìwé 2

Ojú ìwé 2

Báwo Ni A Ṣe Lè Gbẹ́kẹ̀ Lé Sáyẹ́ǹsì Tó? 3-12

Sáyẹ́ǹsì ti jẹ́ ipá kan fún ìtẹ̀síwájú ní ọ̀pọ̀ ẹ̀ka ìdáwọ́lé. Ṣùgbọ́n ṣé ó yẹ kí a máa wo àwọn onímọ̀ sáyẹ́ǹsì bí ẹni tí kò lè ṣàṣìṣe? Mímẹ́nuba iyèméjì díẹ̀ lè ràn ọ́ lọ́wọ́ láti túbọ̀ ní èrò tó wà déédéé, gẹ́gẹ́ bí àwọn àpilẹ̀kọ wọ̀nyí ṣe fi hàn.

Kí Ló Ṣẹlẹ̀ sí Ẹ̀yà Apache? 13

Kí ló jẹ́ òtítọ́ nípa àwọn ènìyàn tí ó gbàfiyèsí wọ̀nyí? Ipò wo ni wọ́n wà lónìí?

Àwọn Kristẹni àti Ètò Kẹ́lẹ́gbẹ́mẹgbẹ́ 22

Báwo ni ètò kẹ́lẹ́gbẹ́mẹgbẹ́ ṣe bẹ̀rẹ̀? Èé ṣe tó fi tàn dénú àwọn ìsìn Kirisẹ́ńdọ̀mù? Irú ojú wo ló yẹ kí àwọn Kristẹni tòótọ́ fi wo ètò kẹ́lẹ́gbẹ́mẹgbẹ́?

[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]

Nípasẹ̀ ìyọ̀ǹda onínúure Arizona Historical Society/Tucson, AHS#78167

[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]

Ọkọ̀ agbénilọgbénibọ̀ tí ń gbéra lẹ́yìn ìwé: Fọ́tò NASA

    Yorùbá Publications (1987-2026)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́