Àwọn Wo Ló Ń Ṣe Ìfẹ́ Jèhófà Lóde Òní? Àwọn Wo Ló Ń Ṣe Ìfẹ́ Jèhófà Lóde Òní? Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ òǹṣèwé sí Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Kí Ni Ọlọ́run Ń Fẹ́? IRÚ ÈÈYÀN TÍ A JẸ́ Ẹ̀KỌ́ 1 Irú Èèyàn Wo Ni Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà? Ẹ̀KỌ́ 2 Kí Nìdí Tí Wọ́n Fi Ń Pè Wá Ní Ẹlẹ́rìí Jèhófà? Ẹ̀KỌ́ 3 Báwo Ni A Ṣe Wá Mọ Òtítọ́ Tí Bíbélì Fi Kọ́ni? Ẹ̀KỌ́ 4 Kí Nìdí Tí A Fi Ṣe Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun? IṢẸ́ WA Ẹ̀KỌ́ 5 Kí Lo Máa Gbádùn Láwọn Ìpàdé Wa? Ẹ̀KỌ́ 6 Àǹfààní Wo La Máa Rí Tá A Bá Ń Bá Àwọn Tá A Jọ Jẹ́ Kristẹni Ṣọ̀rẹ́? Ẹ̀KỌ́ 7 Kí Là Ń Kọ́ Láwọn Ìpàdé Wa? Ẹ̀KỌ́ 8 Kí Nìdí Tá A Fi Ń Múra Dáadáa Nígbà Tá A Bá Ń Lọ sí Àwọn Ìpàdé Wa? Ẹ̀KỌ́ 9 Ọ̀nà Wo Ló Dáa Jù Láti Gbà Múra Ìpàdé Ìjọ Sílẹ̀? Ẹ̀KỌ́ 10 Kí Ni Ìjọsìn Ìdílé? Ẹ̀KỌ́ 11 Kí Nìdí Tí A Fi Ń Lọ sí Àwọn Àpéjọ Ńlá? Ẹ̀KỌ́ 12 Báwo La Ṣe Ṣètò Iṣẹ́ Ìwàásù Ìjọba Ọlọ́run? Ẹ̀KỌ́ 13 Àwọn Wo Ni Aṣáájú-Ọ̀nà? Ẹ̀KỌ́ 14 Àwọn Ilé Ẹ̀kọ́ Tó Wà fún Àwọn Aṣáájú-Ọ̀nà ÈTÒ ÌJỌSÌN WA Ẹ̀KỌ́ 15 Báwo Ni Àwọn Alàgbà Ṣe Ń Ran Ìjọ Lọ́wọ́? Ẹ̀KỌ́ 16 Kí Ni Ojúṣe Àwọn Ìránṣẹ́ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́? Ẹ̀KỌ́ 17 Báwo Ni Àwọn Alábòójútó Àyíká Ṣe Ń Ràn Wá Lọ́wọ́? Ẹ̀KỌ́ 18 Báwo La Ṣe Ń Ṣèrànwọ́ fún Àwọn Ará Wa Tí Àjálù Bá? Ẹ̀KỌ́ 19 Ta Ni Ẹrú Olóòótọ́ àti Olóye? Ẹ̀KỌ́ 20 Ọ̀nà Wo Ni Ìgbìmọ̀ Olùdarí Gbà Ń Ṣiṣẹ́ Lóde Òní? Ẹ̀KỌ́ 21 Ibo Là Ń Pè Ní Bẹ́tẹ́lì? Ẹ̀KỌ́ 22 Kí Là Ń Ṣe ní Àwọn Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Wa? Ẹ̀KỌ́ 23 Báwo La Ṣe Ń Kọ Àwọn Ìwé Wa, Tí A sì Ń Túmọ̀ Wọn? Ẹ̀KỌ́ 24 Báwo La Ṣe Ń Rí Owó fún Iṣẹ́ Wa Kárí Ayé? Ẹ̀KỌ́ 25 Kí Nìdí Tá A Fi Ń Kọ́ Àwọn Gbọ̀ngàn Ìjọba, Báwo La sì Ṣe Ń Kọ́ Wọn? Ẹ̀KỌ́ 26 Kí La Lè Ṣe Láti Máa Tọ́jú Gbọ̀ngàn Ìjọba Wa? Ẹ̀KỌ́ 27 Báwo Ni Ibi Ìkówèésí Gbọ̀ngàn Ìjọba Ṣe Ń Ṣe Wá Láǹfààní? Ẹ̀KỌ́ 28 Kí Ló Wà Lórí Ìkànnì Wa? Ṣé Wàá Ṣe Ìfẹ́ Jèhófà?