ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • syr25 ojú ìwé 2
  • Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2025

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2025
  • Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé ti Ọdún 2025
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2024
    Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé ti Ọdún 2024
  • Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Mélòó Ló Wà Kárí Ayé?
    Àwọn Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Sábà Máa Ń Béèrè Nípa Ẹlẹ́rìí Jèhófà
  • Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2023
    Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé ti Ọdún 2023
  • Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2021
    2021 Ìròyìn Ọdún Iṣẹ́ Ìsìn Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé
Àwọn Míì
Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé ti Ọdún 2025
syr25 ojú ìwé 2

Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2025

  • Iye Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà: 84

  • Iye Orílẹ̀-Èdè Tó Ròyìn: 241

  • Iye Ìjọ: 119,652

  • Àwọn Tó Wá Síbi Ìrántí Ikú Kristi Kárí Ayé: 20,635,015

  • Àwọn Tó Jẹ Ohun Ìṣàpẹẹrẹ Kárí Ayé: 24,576

  • Iye Akédea: 9,205,326

  • Ìpíndọ́gba Akéde Tó Ń Wàásù Lóṣooṣù: 9,047,083

  • Iye Tá A Fi Pọ̀ Ju Ti Ọdún 2024: 2.5

  • Iye Àwọn Tó Ṣèrìbọmib: 304,643

  • Ìpíndọ́gba Aṣáájú-Ọ̀nà Déédééc Lóṣooṣù: 1,743,567

  • Ìpíndọ́gba Aṣáájú-Ọ̀nà Olùrànlọ́wọ́ Lóṣooṣù: 864,870

  • Ìpíndọ́gba Àwọn Tá À Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélìd Lóṣooṣù: 7,603,182

Ọdún iṣẹ́ ìsìn 2025 bẹ̀rẹ̀ láti September 1, 2024, sí August 31, 2025.

a Akéde ni ẹni tó ń kéde tàbí tó ń wàásù ìhìn rere Ìjọba Ọlọ́run déédéé. (Mátíù 24:14) Tó o bá fẹ́ àlàyé nípa bá a ṣe mọ iye àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà, wo àpilẹ̀kọ náà “Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Mélòó Ló Wà Kárí Ayé?” lórí jw.org.

b Tó o bá fẹ́ mọ̀ sí i nípa àwọn nǹkan tẹ́nì kan máa ṣe kó tó lè ṣèrìbọmi kó sì di Ẹlẹ́rìí Jèhófà, wo àpilẹ̀kọ náà “Báwo Ni Mo Ṣe Lè Di Ẹlẹ́rìí Jèhófà?” lórí jw.org.

c Aṣáájú-ọ̀nà ni Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan tó ti ṣèrìbọmi, tó níwà tó dáa, tó sì pinnu láti máa lo iye wákàtí kan pàtó lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù ìhìn rere lóṣooṣù.

d Tó o bá fẹ́ mọ̀ sí i, wo àpilẹ̀kọ tá a pè ní “Kí Ni Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Máa Ń Kọ́ Àwọn Èèyàn?” lórí jw.org.

    Yorùbá Publications (1987-2026)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́