Ṣé ìmọ̀ràn Jésù lè ṣe wá láǹfààní lónìí?
“Gbogbo ohun tí ẹ bá fẹ́ kí àwọn èèyàn ṣe sí yín ni kí ẹ̀yin náà máa ṣe sí wọn.”—Mátíù 7:12.
Jésù tún kọ́ wa pé
Àníyàn wa máa dín kù, tá ò bá da àníyàn tòní pọ̀ mọ́ tọ̀la.—Mátíù 6:34.
Ó yẹ ká máa dárí ji ọmọnìkejì wa.—Mátíù 6:14, 15.
Wo fídíò Ìhìn Rere Látọ̀dọ̀ Jésù lórí jw.org/yo.
© 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania